Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wá mú burẹdi náà, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun, ó bá pín in fún àwọn eniyan tí ó jókòó. Bákan náà ni ó ṣe sí ẹja, ó fún olukuluku bí ó ti ń fẹ́.

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:11 ni o tọ