Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 5:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Jesu dá wọn lóhùn pé, “Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé, Ọmọ kò lè dá nǹkankan ṣe yàtọ̀ sí ohun tí ó bá rí tí Baba ń ṣe. Àwọn ohun tí Ọmọ rí pé Baba ń ṣe ni òun náà ń ṣe.

Ka pipe ipin Johanu 5

Wo Johanu 5:19 ni o tọ