Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, Jesu rí ọkunrin náà ninu Tẹmpili, ó wí fún un pé, “O rí i pé ara rẹ ti dá nisinsinyii, má dẹ́ṣẹ̀ mọ́ kí ohun tí ó burú ju èyí lọ má baà bá ọ.”

Ka pipe ipin Johanu 5

Wo Johanu 5:14 ni o tọ