Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 4:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba ọmọ náà mọ̀ pé àkókò náà gan-an ni Jesu sọ fún òun pé, “Ọmọ rẹ yóo yè.” Òun ati gbogbo ilé rẹ̀ bá gba Jesu gbọ́.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:53 ni o tọ