Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 4:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu tún lọ sí ìlú Kana ti Galili níbi tí ó ti sọ omi di ọtí ní ìjelòó. Ìjòyè kan wà ní Kapanaumu tí ọmọ rẹ̀ ń ṣàìsàn.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:46 ni o tọ