Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Arabinrin, gbà mí gbọ́! Àkókò ń bọ̀ tí ó jẹ́ pé, ati ní orí òkè yìí ni, ati ní Jerusalẹmu ni, kò ní sí ibi tí ẹ óo ti máa sin Baba mọ́.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:21 ni o tọ