Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá a lóhùn pé, “Bí ó bá jẹ́ pé o mọ ẹ̀bùn Ọlọrun ati ẹni tí ó wí fún ọ pé, ‘Fún mi ní omi mu,’ Ìwọ ìbá bèèrè omi ìyè lọ́wọ́ rẹ̀, òun ìbá sì fún ọ.”

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:10 ni o tọ