Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Farisi gbọ́ pé àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu ń pọ̀ ju àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu lọ; ati pé Jesu ń ṣe ìrìbọmi fún ọpọlọpọ eniyan ju Johanu lọ.

Ka pipe ipin Johanu 4

Wo Johanu 4:1 ni o tọ