Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 21:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún wọn pé, “Ẹ wá jẹun.” Kò sí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn tí ó bi í pé, “Ta ni ọ́?” Wọ́n mọ̀ pé Oluwa ni.

Ka pipe ipin Johanu 21

Wo Johanu 21:12 ni o tọ