Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 20:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá wí fún Tomasi pé, “Mú ìka rẹ wá, wo ọwọ́ mi, mú ọwọ́ rẹ wá kí o fi kan ẹ̀gbẹ́ mi. Má ṣe alaigbagbọ mọ́, ṣugbọn gbàgbọ́.”

Ka pipe ipin Johanu 20

Wo Johanu 20:27 ni o tọ