Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ọtí tí ó bá dùn ni gbogbo eniyan kọ́ ń gbé kalẹ̀. Nígbà tí àwọn eniyan bá ti mu ọtí yó tán, wọn á wá gbé ọtí èyí tí kò dára tóbẹ́ẹ̀ wá. Ṣugbọn ìwọ fi àtàtà ọtí yìí pamọ́ di àkókò yìí!”

Ka pipe ipin Johanu 2

Wo Johanu 2:10 ni o tọ