Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 19:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu tún jáde lọ sóde, ó sọ fún àwọn Juu pé, “Mò ń mú un tọ̀ yín bọ̀ wá sóde, kí ẹ lè mọ̀ pé èmi kò rí i pé ó jẹ̀bi ohunkohun.”

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:4 ni o tọ