Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Jesu ti gba ọtí náà tán, ó wí pé, “Ó ti parí!”Lẹ́yìn náà ó tẹrí ba, ó bá dákẹ́.

Ka pipe ipin Johanu 19

Wo Johanu 19:30 ni o tọ