Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 18:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Simoni Peteru tí ó ní idà kan fà á yọ, ó bá ṣá ẹrú Olórí Alufaa, ó gé e létí ọ̀tún. Maliku ni orúkọ ẹrú náà.

Ka pipe ipin Johanu 18

Wo Johanu 18:10 ni o tọ