Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo ti fi orúkọ rẹ han àwọn eniyan tí o fún mi ninu ayé. Tìrẹ ni wọ́n, ìwọ ni o wá fi wọ́n fún mi. Wọ́n sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Johanu 17

Wo Johanu 17:6 ni o tọ