Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Jesu ti sọ ọ̀rọ̀ wọnyi tán, ó gbé ojú sókè ọ̀run, ó ní, “Baba, àkókò náà dé! Jẹ́ kí ògo rẹ hàn lára Ọmọ, kí ògo Ọmọ náà lè hàn lára rẹ.

Ka pipe ipin Johanu 17

Wo Johanu 17:1 ni o tọ