Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Ẹ̀mí òtítọ́ tí mo wí bá dé, yóo tọ yín sí ọ̀nà òtítọ́ gbogbo. Nítorí kò ní sọ ọ̀rọ̀ ti ara rẹ̀; gbogbo ohun tí ó bá gbọ́ ni yóo sọ. Yóo sọ àwọn ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ fun yín.

Ka pipe ipin Johanu 16

Wo Johanu 16:13 ni o tọ