Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 12:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá tún sọ pé, “Ọkàn mí dàrú nisinsinyii. Kí ni ǹ bá wí? Ọkàn kan ń sọ pé kí n wí pé, ‘Baba, yọ mí kúrò ninu àkókò yìí.’ Ṣugbọn nítorí àkókò yìí gan-an ni mo ṣe wá sí ayé.

Ka pipe ipin Johanu 12

Wo Johanu 12:27 ni o tọ