Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 11:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí Jesu tún wú, ó bá lọ síbi ibojì. Ninu ihò òkúta ni ibojì náà wà, òkúta sì wà ní ẹnu ọ̀nà rẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu 11

Wo Johanu 11:38 ni o tọ