Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan tí ń jẹ́ Lasaru ń ṣàìsàn. Ní Bẹtani ni ó ń gbé, ní ìlú kan náà pẹlu Maria ati Mata arabinrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu 11

Wo Johanu 11:1 ni o tọ