Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Alágbàṣe tí kì í ṣe olùṣọ́-aguntan, tí kì í sìí ṣe olówó aguntan, bí ó bá rí ìkookò tí ń bọ̀, a fi àwọn aguntan sílẹ̀, a sálọ. Ìkookò a gbé ninu àwọn aguntan lọ, a sì tú wọn ká,

Ka pipe ipin Johanu 10

Wo Johanu 10:12 ni o tọ