Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 1:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu yipada, tí ó rí wọn tí wọn ń tẹ̀lé òun, ó bi wọn pé, “Kí ni ẹ̀ ń wá?”Wọ́n ní, “Rabi, níbo ni ò ń gbé?” (Ìtumọ̀ “Rabi” ni “Olùkọ́ni.”)

Ka pipe ipin Johanu 1

Wo Johanu 1:38 ni o tọ