Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ti Ọlọrun ni àwa; Ẹni tí ó bá mọ Ọlọrun ń gbọ́ tiwa; ẹni tí kì í bá ṣe ti Ọlọrun kò ní gbọ́ tiwa. Ọ̀nà tí a fi mọ Ẹ̀mí òtítọ́ ati ẹ̀mí ìtànjẹ yàtọ̀ nìyí.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 4

Wo Johanu Kinni 4:6 ni o tọ