Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà tí a óo fi mọ Ẹ̀mí Ọlọrun nìyí: gbogbo ẹni tí ó bá jẹ́wọ́ pé Jesu Kristi wá sáyé gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́ran-ara jẹ́ ẹni tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 4

Wo Johanu Kinni 4:2 ni o tọ