Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà tí a fi lè mọ àwọn ọmọ Ọlọrun yàtọ̀ sí àwọn ọmọ Èṣù nìyí: gbogbo ẹni tí kò bá ṣe iṣẹ́ òdodo tí kò sì fẹ́ràn arakunrin rẹ̀ kò wá láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 3

Wo Johanu Kinni 3:10 ni o tọ