Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí a bá ń gbé inú ìmọ́lẹ̀, bí òun náà ti wà ninu ìmọ́lẹ̀, a ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu ara wa, ẹ̀jẹ̀ Jesu Ọmọ rẹ̀ sì ti wẹ gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa nù kúrò lára wa.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 1

Wo Johanu Kinni 1:7 ni o tọ