Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó ti wà láti ìṣẹ̀dálẹ̀ ayé, ohun tí a ti gbọ́, tíí ṣe ọ̀rọ̀ ìyè, tí a ti fi ojú ara wa rí, tí a wò dáradára, tí a fi ọwọ́ wa dìmú, òun ni à ń sọ fun yín.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 1

Wo Johanu Kinni 1:1 ni o tọ