Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ yín fún ara yín, ẹ máa gbadura fún ara yín kí ẹ lè ní ìwòsàn. Adura àtọkànwá olódodo lágbára, nítorí Ọlọrun a máa fi àṣẹ sí i.

Ka pipe ipin Jakọbu 5

Wo Jakọbu 5:16 ni o tọ