Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti pé àwọn tí ó bá ní ìfaradà ni à ń pè ní ẹni ibukun. Ẹ ti gbọ́ nípa Jobu, bí ó ti ní ìfaradà, ẹ sì mọ bí Oluwa ti jẹ́ kí ó yọrí sí fún un. Nítorí oníyọ̀ọ́nú ati aláàánú ni Oluwa.

Ka pipe ipin Jakọbu 5

Wo Jakọbu 5:11 ni o tọ