Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí ọkàn yín bàjẹ́, ẹ ṣọ̀fọ̀, ẹ sọkún; ẹ má rẹ́rìn-ín mọ́, ńṣe ni kí ẹ fajúro. Ẹ máa banújẹ́ dípò yíyọ̀ tí ẹ̀ ń yọ̀.

Ka pipe ipin Jakọbu 4

Wo Jakọbu 4:9 ni o tọ