Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin àgbèrè, ẹ kò mọ̀ pé ìbá ayé ṣọ̀rẹ́ níláti jẹ́ ìbá Ọlọrun ṣọ̀tá? Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ti yàn láti jẹ́ ọ̀tá Ọlọrun.

Ka pipe ipin Jakọbu 4

Wo Jakọbu 4:4 ni o tọ