Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 4:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Ṣugbọn ẹ̀ ń lérí, ẹ̀ ń fọ́nnu; irú ìlérí báyìí kò dára.

17. Nítorí náà, ẹni tí ó bá mọ rere í ṣe tí kò ṣe é, ẹ̀ṣẹ̀ ni ó ń gbà.

Ka pipe ipin Jakọbu 4