Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ óo máa fi ojurere wo ẹni tí ó wọ aṣọ dídán, ẹ óo sọ fún un pé, “Wá jókòó níbi dáradára yìí.” Ṣugbọn ẹ óo wá sọ fún talaka pé, “Dúró níbẹ̀, tabi wá jókòó nílẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ mi níhìn-ín.”

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:3 ni o tọ