Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará mi olùfẹ́ ọ̀wọ́n, mo fẹ́ kí ẹ mọ nǹkankan: eniyan níláti tètè gbọ́ ọ̀rọ̀, ṣugbọn kí ó lọ́ra láti désì pada, kí ó sì lọ́ra láti bínú.

Ka pipe ipin Jakọbu 1

Wo Jakọbu 1:19 ni o tọ