Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jakọbu 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí oòrùn bá yọ, tí ó mú, koríko á rọ, òdòdó rẹ̀ á sì rẹ̀, òdòdó tí ó lẹ́wà tẹ́lẹ̀ á wá ṣègbé. Bẹ́ẹ̀ gan-an ni ọlọ́rọ̀ yóo parẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jakọbu 1

Wo Jakọbu 1:11 ni o tọ