Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli náà bá mú àwo turari yìí, ó bu iná láti orí pẹpẹ ìrúbọ kún inú rẹ̀, ó bá jù ú sí orí ilẹ̀ ayé. Ààrá bá bẹ̀rẹ̀ sí sán, mànàmáná ń kọ, ilẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí mì tìtì.

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:5 ni o tọ