Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń kìlọ̀ fún gbogbo ẹni tí ó bá gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ ìwé yìí. Bí ẹnikẹ́ni bá fi nǹkankan kún un, Ọlọrun yóo fi kún àwọn ìyà rẹ̀ tí a ti kọ sinu ìwé yìí.

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:18 ni o tọ