Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 12:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ máa yọ̀, ẹ̀yin ọ̀run ati ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé inú wọn. Ó ṣe fun yín, ayé, ati fún òkun! Nítorí Èṣù ti dé sáàrin yín. Inú rẹ̀ ń ru, nítorí ó mọ̀ pé ìgbà díẹ̀ ni ó kù fún òun.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:12 ni o tọ