Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ó ń bọ̀ ninu awọsanma, gbogbo eniyan ni yóo sì rí i. Àwọn tí wọ́n gún un lọ́kọ̀ náà yóo rí i. Gbogbo ẹ̀yà ilẹ̀ ayé yóo dárò nígbà tí wọ́n bá rí i. Amin! Àṣẹ!

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:7 ni o tọ