Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo rí i, mo ṣubú lulẹ̀ lẹ́sẹ̀ rẹ̀ bí ẹni tí ó kú. Ó bá gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lé mi. Ó ní, “Má bẹ̀rù. Èmi ni ẹni kinni ati ẹni ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:17 ni o tọ