Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru bá gbéra, ó tẹ̀lé wọn. Nígbà tí ó dé Jọpa, ó lọ sí iyàrá lókè. Gbogbo àwọn opó bá yí i ká, wọ́n ń sunkún, wọ́n ń fi àwọn ẹ̀wù ati aṣọ tí Dọkasi máa ń rán fún wọn nígbà tí ó wà láàyè han Peteru.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:39 ni o tọ