Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Anania bá lọ, ó wọ inú ilé náà, ó fi ọwọ́ kan Saulu. Ó ní, “Saulu arakunrin mi, Oluwa ni ó rán mi sí ọ. Jesu tí ó farahàn ọ́ ní ojú ọ̀nà tí o gbà wá, ni ó rán mi wá, kí o lè tún ríran, kí o sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:17 ni o tọ