Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kán wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Simoni, tí ó ti máa ń pidán ní ìlú náà. Èyí jẹ́ ìyanu fún àwọn ará Samaria, wọ́n ní ẹni ńlá ni ọkunrin náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 8:9 ni o tọ