Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí àtíbàbà Moleki ni ẹ gbé rù,ati ìràwọ̀ Refani oriṣa yín,àwọn ère tí ẹ ṣe láti máa foríbalẹ̀ fún?N óo le yín lọ sí ìgbèkùn, ẹ óo kọjá Babiloni.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:43 ni o tọ