Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Peteru ti ń bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Johanu wà lọ́dọ̀ rẹ̀, àwọn alufaa ati olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ Tẹmpili ati àwọn Sadusi bá dé.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 4:1 ni o tọ