Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru bá sọ fún un pé, “N kò ní fadaka tabi wúrà, ṣugbọn n óo fún ọ ní ohun tí mo ní. Ní orúkọ Jesu Kristi ti Nasarẹti, máa rìn.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:6 ni o tọ