Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Peteru rí wọn, ó bi àwọn eniyan pé, “Ẹ̀yin eniyan Israẹli, kí ló dé tí èyí fi yà yín lẹ́nu? Kí ló dé tí ẹ fi tẹjú mọ́ wa bí ẹni pé nípa agbára wa tabi nítorí pé a jẹ́ olùfọkànsìn ni a fi mú kí ọkunrin yìí rìn?

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:12 ni o tọ