Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Fún ọdún meji gbáko ni Paulu fi gbé ninu ilé tí ó gbà fúnra rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ó ń gba gbogbo àwọn tí ó ń wá rí i.

31. Ó ń waasu ìjọba Ọlọrun. Ó ń kọ́ àwọn eniyan nípa Oluwa Jesu Kristi láì bẹ̀rù ohunkohun. Ẹnikẹ́ni kò sì dí i lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28