Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni pé Mesaya níláti jìyà; àtipé òun ni yóo kọ́ jí dìde kúrò ninu òkú tí yóo sì kéde iṣẹ́ ìmọ́lẹ̀ fún àwọn eniyan Ọlọrun ati fún àwọn tí kì í ṣe Juu.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:23 ni o tọ