Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo kọ́kọ́ waasu fún àwọn tó wà ní Damasku, lẹ́yìn náà mo waasu fún àwọn tó wà ní Jerusalẹmu, ati ní gbogbo ilẹ̀ Judia, ati fún àwọn tí kì í ṣe Juu. Mò ń kéde pé kí wọ́n ronupiwada, kí wọ́n yipada sí Ọlọrun, kí wọn máa ṣe ohun tí ó yẹ ẹni tí ó ti ronupiwada.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:20 ni o tọ